Alaye ohun ti o njẹ ẹran ikomọjade ati awọn ẹri ti o tọka si i ninu Sunna.Alaye awọn idajọ ẹran ikomọjade pẹlu sisọ awọn majẹmu ti o rọ mọ ọ.Abala yii ni oludanilẹkọ ti jẹ ki a mọ boya a le se ẹran ikomọjade ni ọbẹ, ki a pe awọn eniyan waa jẹ ẹ, tabi dandan ni ki a pin in ni tutu?
Show More
Creators & Guests
We don't know anything about the creators of this podcast yet. You can so they can be credited for this and other podcasts.