Ètò yí wà fún gbogbo onígbàgbọ́ nínú Jésù Krístì tó ní ìfẹ́ láti mú ìyípadà rere bá gbogbo ènìyàn tí ó wà ní gbogbo Orílẹ̀-Èdè àgbáyé. Eto yi yoo maa ru o soke, yi o si maa ko o ni eko lati le mu iyipada wa si aye yi. O ma ko bi o ti ma lo agbara Olorun ati Oro Olorun ninu aye re so Awon Eniyan da omo leyin Kristi. Ti won yo si ma ni iyipada aye won si igbala ati iyipada aye won si igbe-aye Ayo, Alaafia ati Ireti.
Show More
Creators & Guests
We don't know anything about the creators of this podcast yet. You can so they can be credited for this and other podcasts.